Ìmọ́lẹ̀ àti Àwọ̀

Ìmọ́lẹ̀ àti Àwọ̀

Oríṣiríṣi àwọ̀ tó jojú ní gbèsè ló kúnnú ayé yìí. Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹni tó dá ìmọ́lẹ̀ àti àwọ̀ àti ohun tí àwọn ìṣẹ̀dà yìí ń sọ nípa irú ẹni tí oníṣẹ́ ọnà náà jẹ́.