Àwọn Ìṣẹ̀dá Ọlọ́run Ń Fi Ògo Rẹ̀ Hàn

Àwọn Ìṣẹ̀dá Ọlọ́run Ń Fi Ògo Rẹ̀ Hàn

Tó o bá ń fara balẹ̀ kíyè sí àwọn nǹkan tí Ọlọ́run dá, wàá máa mọ ọ̀pọ̀ nǹkan nípa Ẹlẹ́dàá wa, wàá sì di ọ̀rẹ́ rẹ̀.