Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìgbà Ọ̀dọ́ Mi​—Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàtúnṣe?

Ìgbà Ọ̀dọ́ Mi​—Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàtúnṣe?

Thalila àti José rí i pé kì í pẹ́ tí àṣìṣe kan fi máa ń mú kéèyàn ṣe àṣìṣe míì. Kí ni wọ́n ṣe kí wọ́n lè ṣàtúnṣe?