Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ṣé Gbogbo Ẹ̀sìn Ni Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà?

Ṣé Gbogbo Ẹ̀sìn Ni Ọlọ́run Tẹ́wọ́ Gbà?

Ṣé gbogbo ẹ̀sìn ló ń kọ́ni ní òtítọ́? Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀, kí nìdí tí ìgbàgbọ́ àwọn èèyàn ò fi ṣọ̀kan, báwo la sì ṣe lè mọ̀ bóyá Ọlọ́run tẹ́wọ́ gba ìjọsìn wa?