Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà Máa Bá Àwọn Èèyàn Gidi Ṣọ̀rẹ́! TẸ̀ Ẹ̣́ Máa Bá Àwọn Èèyàn Gidi Ṣọ̀rẹ́! Ìwọ àti òbí ẹ lè bá àwọn àgbàlagbà inú ìjọ yín ṣọ̀rẹ́. Wà á jáde Pa Dà Èyí Tó Kàn O Tún Lè Wo Become Jehovah's Friend Bó O Ṣe Lè Ní Ọ̀rẹ́ Ta lo lè mú lọ́rẹ̀ẹ́ nínú ìjọ? OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Eré Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.