Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà À Ń Wàásù fún Gbogbo Onírúurú Èèyàn TẸ̀ Ẹ̣́ À Ń Wàásù fún Gbogbo Onírúurú Èèyàn Àwọn wo ló yẹ ká wàásù fún? Jẹ́ ká wò ó! Wà á jáde Pa Dà Èyí Tó Kàn O Tún Lè Wo Become Jehovah’s Friend—Sing With Us À Ń Wàásù fún Gbogbo Onírúurú Èèyàn (Orin 142) Ṣé gbogbo èèyàn lo máa ń wàásù fún, láìka bí wọ́n ṣe rí sí? OHUN TÓ WÀ LÓRÍ ÌKÀNNÌ Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Eré Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.