Become Jehovah’s Friend—Activities

Máa Ṣaájò Àlejò

Yorùbá
Máa Ṣaájò Àlejò
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/501700115/univ/art/501700115_univ_sqr_xl.jpg

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Máa Ṣaájò Àlejò

Máa Ṣaájò Àlejò

Ẹ̀yin òbí, ẹ fi eré yìí jíròrò bí ìdílé yín ṣe lè túbọ̀ máa ṣaájò àlejò.

Ẹ̀yin òbí, ẹ ka Róòmù 12:13 kẹ́ ẹ sì jíròrò ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ yín.

Wa eré yìí jáde, kó o sì tẹ̀ ẹ́ sórí ìwé.

Lẹ́yìn tẹ́ ẹ bá wo fídíò náà, ẹ fi àwọn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀ jíròrò bí ìdílé yín ṣe lè túbọ̀ máa ṣaájò àlejò. Ẹ bá àwọn ọmọ yín gé àwọn àwòrán róbótó yìí. Ẹ lè jọ ya àwòrán tàbí kẹ́ ẹ kọ ọ̀rọ̀ sínú àwọn àwòrán róbótó náà, kẹ́ ẹ wá ní kí wọ́n fún ọ̀rẹ́ wọn.