Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àyíká 2025-2026 Tí Aṣojú Ẹ̀ka Ọ́fí ìsì Máa Bá Wa Ṣe
“Gbọ́ Ohun Tí Ẹ̀mí Ń Sọ fún Àwọn Ìjọ”
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ àwọn nǹkan tá a máa gbádùn ní àárọ̀ àti ọ̀sán àpéjọ àyíká tí aṣojú ẹ̀ka ọ́fí ìsì máa bá wa ṣe.
Wá Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè Yìí
A máa dáhùn àwọn ìbéèrè yìí bá a ṣe ń bá àpéjọ náà lọ.

