Orí kẹtàdínlógún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Ṣé Ọlọ́run máa ń dáhùn àdúrà wa lóòótọ́? Tó bá máa ń ṣe bẹ́ẹ̀, ọ̀nà wo ló máa ń gbà ṣe é?