Orí kẹtàlá ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Wo ohun tí Bíbélì sọ nípa àṣìlò ẹ̀jẹ̀ àti bí ọ̀nà kan ṣoṣo tó tọ́ láti lò ó ṣe lè gba ẹ̀mí wa là.