Orí kẹta ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Ọlọ́run máa lo Ìjọba rẹ̀ láti mú kí ayé yìí rí bó ṣe fẹ́, yóò sì fòpin sí gbogbo ìṣòro tó ń yọ aráyé lẹ́nu.