Orí kẹta ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Ṣàyẹ̀wò kó o lè mọ ẹni tó ń darí ayé yìí, tó sì wà nídìí gbogbo nǹkan burúkú tó ń ṣẹlẹ̀.