Orí kẹjọ ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Wo ohun tó mú kí àwọn tó máa ṣàkóso lọ́run tóótun láti ṣe iṣẹ́ tí Ọlọ́run yàn fún wọn.