Orí keje ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Gbé àwọn ìdí pàtàkì tó fi yẹ ká ní ìgbàgbọ́ pé àjíǹde máa wà yẹ̀wò.