Orí keje ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Wò ó bóyá ó burú kí inú ẹni bà jẹ́ téèyàn ẹ̀ bá kú, kó o sì tún kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tí Ọlọ́run máa ṣe sí ìbànújẹ́ tó máa ń bá wa.