Orí kẹẹ̀ẹ́dógún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Ṣé gbogbo ìsìn ni Ọlọ́run fọwọ́ sí? Tí kì í bá ṣe gbogbo wọn, báwo lo ṣe lè dá ìsìn tòótọ́ mọ̀?