Orí kẹfà ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Kí nìdí tí Ádámù, ọkùnrin tí Ọlọ́run kọ́kọ́ dá fi kú? Ṣé ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí àwa èèyàn máa kú? Gbọ́ ohun tí Bíbélì sọ.