Orí kẹrìndínlógún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Ṣé Ọlọ́run fọwọ́ sí i ká máa lo ère tá a bá ń jọ́sìn? Ṣé ó fọwọ́ sí i ká máa ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí àtàwọn ayẹyẹ ìsìn? Wo àwọn ìlànà Bíbélì tó dá lórí ọ̀rọ̀ yìí.