Orí kejì ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Fi àpilẹ̀kọ yìí ṣàyẹ̀wò ìdí tí Bíbélì fi jẹ́ ìwé tó wúlò fún wa, tí ọ̀rọ̀ inú rẹ̀ sì ṣeé gbára lé.