Orí kẹsàn-án ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Ǹjẹ́ Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ pé àwọn nǹkan rere máa ṣẹlẹ̀ ní “àwọn ọjọ́ ìkẹyìn”? Àwọn nǹkan rere wo ló máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ìgbà yẹn? Gbé ohun tí Bíbélì sọ yẹ̀ wò.