Orí kìíní ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé.

Yẹ àpilẹ̀kọ yìí wò kó o lè mọ ìdí tó fi ṣe pàtàkì pé ká mọ orúkọ Ọlọ́run ká sì máa lò ó.