Àwọn ohun tá a fi ń kẹ́kọ̀ọ́ yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè máa kọ́ ohun tó wà nínú Bíbélì ní ṣísẹ̀-n-tẹ̀-lé. Ó máa jẹ́ kó o gbádùn ìkẹ́kọ̀ọ́ náà, wàá sì rí ìdáhùn tó ń tẹ́ni lọ́rùn sí àwọn ìbéèrè ẹ.