Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìtàn Nípa Bíbélì

Orí àti Ẹsẹ—Ta Ló Fi Wọ́n Sínú Bíbélì?

Kí nìdí tí ọ̀nà tí wọ́n gbà pín Bíbélì yìí fi gbéṣẹ́?

Bíbélì Bọ́ Lọ́wọ́ Àwọn Alátakò

Ọ̀pọ̀ olóṣèlú àtàwọn aṣáájú ẹ̀sìn tí gbìyànjú láti mú káwọn èèyàn má ṣe ní Bíbélì, kí wọ́n ṣe ẹ̀dà rẹ̀ tàbí kí wọ́n túmọ̀ rẹ̀. Àmọ́ wọn ò ṣàṣeyọrí.

Ṣe Òótọ́ Ni Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì?

Tó bá jẹ́ pé Ọlọ́run ló ni Bíbélì, á jẹ́ pé kò sí ìwé míì tá a lè fi í wé.

Ṣé Wọ́n Ti Yí Ohun Tó Wà Nínú Bíbélì Pa Dà?

Torí pé ó pẹ́ gan-an tí Bíbélì ti wà, kí ló lè jẹ́ kó dá wa lójú pé ohun tó wà nínú ẹ̀ ò yí pa dà?

Bíbélì Bọ́ Lọ́wọ́ Àwọn Tó Fẹ́ Yí Ọ̀rọ̀ Inú Rẹ̀ Pa Dà

Àwọn aláìdáa kan tí gbìyànjú láti yí ọ̀rọ̀ inú Bíbélì pa dà. Báwo ni àṣírí ìwà àìdáa wọn ṣe tú, tí wọn ò sì ṣàṣèyọrí?