Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n àti Ìṣẹ̀dá

Àwọn Ọ̀dọ́ Sọ Pé Ọlọ́run Wà Lóòótọ́

Àwọn ọ̀dọ́ kan sọ ohun tó jẹ́ kó dá wọn lójú pé Ẹlẹ́dàá kan wà lóòótọ́ nínu fídíò oníṣẹ̀ẹ́jú mẹ́ta yìí.

Kẹ́míkà Àgbàyanu Tó Ń Jẹ́ Carbon

Kò sí nǹkan mí ì tó ṣàǹfààní fún ìwàláàyè àwọn nǹkan ẹlẹ́mìí bíi carbon. Kí nìdí tó fi rí bẹ́ẹ̀, kó ló sì mú kó ṣe pàtàkì?

Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?—Apá 1: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Gbà Pé Ọlọ́run Wà?

Ǹjẹ́ wàá fẹ́ mọ bó o ṣe lè túbọ̀ máa fi ìdánilójú ṣàlàyé ìdí tó o fi gbà gbọ́ pé Ọlọ́run wà fáwọn ẹlòmíì? Kà nípa àwọn ohun tó o lè fi fèsì tí ẹnì kan bá sọ pé ìgbàgbọ́ tó o ní pé Ọlọ́run wà kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀.

Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?—Apá 3: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Gbà Pé Ọlọ́run Wà?

Ṣé ó yẹ kó o di alátakò ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì kó o tó lè gbà pé Ọlọ́run ló dá ohun gbogbo?

Ṣé Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Tọ̀nà àbí Ẹlẹ́dàá Kan Wà?—Apá 4: Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ṣàlàyé Ohun Tí Mo Gbà Gbọ́ Nípa Ìṣẹ̀dá?

Kò dìgbà tó o bá tó di ọ̀gá nídìí ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì kó o tó lè ṣàlàyé ìdí tó o fi rò pé ó bọ́gbọ́n mu ká gbà pẹ́ ẹnì kan ló dá gbogbo nǹkan tó wà láyé. Lo àlàyé tó bọ́gbọ́n mu tó wà nínú Bíbélì.

Ṣó Yẹ Kí N Gba Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Gbọ́?

Èwo ló bọ́gbọ́n mu, pé gbogbo nǹkan ṣàdédé wà àbí ẹnì kan ló dá wọn?