Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Bíbélì

Ṣé ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì bá Bíbélì mu? Tí Bíbélì bá sọ̀rọ̀ nípa ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì, ṣé ohun tó sọ máa ń jóòótọ́? Wo àwọn ohun tó wà nínú ayé, kó o tún wo ohun táwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì tó kẹ́kọ̀ọ́ nípa wọn sọ.