Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Kí Ni Mo Lè Gbàdúrà Fún?

Kí Ni Mo Lè Gbàdúrà Fún?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kò sóhun tó ò lè gbàdúrà fún tó bá ṣáà ti bá ìfẹ́ Ọlọ́run mu, bó ṣe wà nínú Bíbélì. “Ohun yòówù tí ì báà jẹ́ tí a bá béèrè ní ìbámu pẹ̀lú ìfẹ́ rẹ̀, ó ń gbọ́ tiwa.” (1 Jòhánù 5:14) Ṣó o lè sọ ohun tó ń dùn ẹ́ lọ́kàn fún Ọlọ́run? Bẹ́ẹ̀ ni. Bíbélì ṣáà sọ pé: “Ẹ tú ọkàn-àyà yín jáde níwájú [Ọlọ́run].”—Psalm 62:8.

Àpẹẹrẹ ohun tó o lè gbàdúrà fún