Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Kí ni Bíbélì fi kọ́ni gan-an? Mú ìbéèrè kan nínú àwọn ìbéèrè tó wà nísàlẹ̀ yìí.

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

Ṣé Màríà Ni Ìyá Ọlọ́run?

Ìwé Mímọ́ àti ìtàn ẹ̀sìn Kristẹni sọ ohun tó jẹ́ òtítọ́ nípa ẹ̀kọ́ yìí.

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

Ṣé Màríà Ni Ìyá Ọlọ́run?

Ìwé Mímọ́ àti ìtàn ẹ̀sìn Kristẹni sọ ohun tó jẹ́ òtítọ́ nípa ẹ̀kọ́ yìí.

Ìgbésí Ayé àti Ìwà Rere

Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́dọ̀ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Bíbélì ń ran ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù èèyàn lọ́wọ́ kárí ayé láti rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè tó ṣe pàtàkì jù lọ. Ṣé wàá fẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára wọn?

Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Níbi gbogbo kárí ayé láwọn èèyàn ti mọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí wọ́n máa ń ṣe fáwọn èèyàn lọ́fẹ̀ẹ́. Wo bí wọ́n ṣe máa ń ṣe é.

Béèrè Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́ ní àkókò àti ibi tó rọrùn fún ẹ.