Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ

KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ

Mánóà

Wa káàdì eré Bíbélì yìí jáde, kó o sì kọ́ nípa Mánóà tó jẹ́ bàbá ọ̀kan lára àwọn tó lágbára jù lọ nínú àwọn tó tíì gbé láyé. Tẹ̀ ẹ́, gé e, ká a sí méjì, kó o sì tọ́jú rẹ̀.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Káàdì Bíbélì Nípa Hánà

Ọlọ́run dáhùn àdúrà pàtó tí Hánà gbà.

Káàdì Bíbélì Nípa Sọ́ọ̀lù Ọba

Onírẹ̀lẹ̀ ni Sọ́ọ̀lù nígbà tó kọ́kọ́ di ọba àkọ́kọ́ ní Ísírẹ́lì.

Káàdì Bíbélì Nípa Gídíónì

Ẹ̀rù kọ́kọ́ ń bà á, àmọ́ ó wá di onígboyà.