Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ

Áárónì

Wa káàdì eré Bíbélì yìí jáde kó o sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹ̀gbọ́n Mósè, ìyẹn Áárónì tó di àlùfáà àgbà àkọ́kọ́ ní Ísírẹ́lì. Tẹ̀ ẹ́ jáde, gé e, ká a sí méjì, kó o sì tọ́jú rẹ̀.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Káàdì Bíbélì Nípa Hánà

Ọlọ́run dáhùn àdúrà pàtó tí Hánà gbà.

Káàdì Bíbélì Nípa Sọ́ọ̀lù Ọba

Onírẹ̀lẹ̀ ni Sọ́ọ̀lù nígbà tó kọ́kọ́ di ọba àkọ́kọ́ ní Ísírẹ́lì.

Káàdì Bíbélì Mánóà

Òun ni bàbá ọ̀kan lára àwọn tó lágbára jù lọ tó tíì gbé láyé.