Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ

IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ

Jèhófà Gba Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Là

Ẹ́KÍSÓDÙ 13:17–15:21

Ìtọ́ni fún Àwọn Òbí: Kí ìdílé rẹ fi àwọn nǹkan yìí kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pa pọ̀.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Yíyàn Láti Sin Jèhófà

Ìtọ́ni yìí máa jẹ́ kó o lè kọ́ àwọn ọmọ rẹ bí wọ́n ṣe lè láyọ̀ tí wọ́n bá ń sin Jèhófà.

Jíjẹ́ Onígboyà

Kọ́ àwọn ọmọ rẹ ní ohun tó máa ń mú kéèyàn nígboyà.

Bí Ẹ̀mí Mímọ́ Ṣe Máa Ń Fún Wa Lágbára Ká Lè Sin Jèhófà

Lo eré yìí láti kọ́ ọmọ rẹ nípa bí Jèhófà ṣe máa ń lo ẹ̀mí mímọ́ rẹ̀ láti fún wa lágbára.