Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ERÉ ALÁWÒRÁN

ERÉ ALÁWÒRÁN

Ta Ló Yàn Láti Sin Jèhófà?

Fàlà láti ibi orúkọ àwọn èèyàn inú Bíbélì síbi àlàyé tó bá irú ẹni tí wọ́n jẹ́ mu. Wá èyí tó yàn láti sin Ọlọ́run nínú àwọn èèyàn náà.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Hánà Ran Sámúẹ́lì Lọ́wọ́ Kó Lè Sin Jèhófà

Eré yìí máa ran àwọn ọmọ ọdún mẹ́ta sí mẹ́fà láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹ̀bùn tí Hánà máa ń fún Sámúẹ́lì lọ́dọọdún.

Dáfídì Nígboyà, Bí Ò Tiẹ̀ Ní Ju Ohun Ìjà Díẹ̀

Mú káàdì tí wọ́n ya àwọn èèyàn inú Bíbélì sí tó bára mu pẹ̀lú èyí tí wọ́n ya àwòrán àwọn nǹkan míì sí.

Dáfídì Wá ní Orúkọ Ọlọ́run

Kọ́ ọmọ rẹ ní ìtumọ̀ orúkọ Ọlọ́run.