Wa eré yìí jáde, kó o sì kọ́ bí wàá ṣe ya àwòrán Ráhábù obìnrin tó ní ìgbàgbọ́.