Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ERÉ ALÁWÒRÁN

Hánà Ran Sámúẹ́lì Lọ́wọ́ Kó Lè Sin Jèhófà

Bá Sámúẹ́lì ṣe aṣọ àwọ̀lékè kan tí kò lápá, irú èyí tí ìyá rẹ̀ máa ń ṣe fún un.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Ta Ló Yàn Láti Sin Jèhófà?

Eré yìí máa ran àwọn ọmọ ọdún mẹ́fà sí mẹ́jọ kí wọ́n lè mọ àwọn èèyàn inú Bíbélì.

Dáfídì Nígboyà, Bí Ò Tiẹ̀ Ní Ju Ohun Ìjà Díẹ̀

Mú káàdì tí wọ́n ya àwọn èèyàn inú Bíbélì sí tó bára mu pẹ̀lú èyí tí wọ́n ya àwòrán àwọn nǹkan míì sí.

Dáfídì Wá ní Orúkọ Ọlọ́run

Kọ́ ọmọ rẹ ní ìtumọ̀ orúkọ Ọlọ́run.