Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Eré Aláwòrán

Wa àwọn eré aláwòrán tó ṣeé tẹ̀ jáde fún ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ìdílé rẹ. Wa eré aláwòrán kọ̀ọ̀kan jáde kó o sì tẹ̀ wọ́n, kẹ́ ẹ parí àwòrán náà nípa síso àwọn àmì tó-tò-tó náà pọ̀ tàbí kẹ́ ẹ kùn àwòrán náà, lẹ́yìn náà kẹ́ ẹ dáhùn àwọn ìbéèrè tó wà níbẹ̀.