Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Kọ Orin Kan Tó Dá Lórí Ìgboyà

Kọ́ orin kan sórí tó máa mú kó o nígboyà.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Ta Lo Máa Fún Níṣìírí?

Eré yìí máa jẹ́ kí àwọn ọmọ ọdún mẹ́jọ sí méjìlá lè ṣètò bí wọ́n ṣe máa fún ẹnì kan níṣìírí.

Àwọn Ànímọ́ Tí Ẹ̀mí Mímọ́ Máa Ń Mú Ká Ní

Eré yìí máa ran àwọn ọmọdé tọ́jọ́ orí wọn jẹ́ mẹ́jọ sí méjìlá lọ́wọ́ láti mọ àwọn ànímọ́ tí ẹ̀mí mímọ́ máa ń mú ká ní.

Àwọn Arákùnrin àti Arábìnrin Wa Ń Mú Ká Lókun

Jẹ́ kí àwọn ọmọ rẹ mọ bí wọ́n ṣe lè ran àwọn ọ̀rẹ́ wọn lọ́wọ́ àti bí àwọn ọ̀rẹ́ wọn ṣe lè ran àwọn náà lọ́wọ́.