Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Ta Lo Máa Fún Níṣìírí?

Fún ẹnì kan níṣìírí kó lè máa sin Jèhófà, bí Ẹlikénà àti Hánà ṣe fún Sámúẹ́lì níṣìírí.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Kọ Orin Kan Tó Dá Lórí Ìgboyà

Kọ́ orin kan tó dá lórí ìgboyà, kí ìwọ àti ìdílé rẹ wá jọ kọ ọ́.

Àwọn Ànímọ́ Tí Ẹ̀mí Mímọ́ Máa Ń Mú Ká Ní

Eré yìí máa ran àwọn ọmọdé tọ́jọ́ orí wọn jẹ́ mẹ́jọ sí méjìlá lọ́wọ́ láti mọ àwọn ànímọ́ tí ẹ̀mí mímọ́ máa ń mú ká ní.

Àwọn Arákùnrin àti Arábìnrin Wa Ń Mú Ká Lókun

Jẹ́ kí àwọn ọmọ rẹ mọ bí wọ́n ṣe lè ran àwọn ọ̀rẹ́ wọn lọ́wọ́ àti bí àwọn ọ̀rẹ́ wọn ṣe lè ran àwọn náà lọ́wọ́.