Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Àwọn Ànímọ́ Tí Ẹ̀mí Mímọ́ Máa Ń Mú Ká Ní

Kọ́ nípa àwọn ànímọ́ mẹ́sàn-án tí ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run máa ń mú ká ní.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Ta Lo Máa Fún Níṣìírí?

Eré yìí máa jẹ́ kí àwọn ọmọ ọdún mẹ́jọ sí méjìlá lè ṣètò bí wọ́n ṣe máa fún ẹnì kan níṣìírí.

Kọ Orin Kan Tó Dá Lórí Ìgboyà

Kọ́ orin kan tó dá lórí ìgboyà, kí ìwọ àti ìdílé rẹ wá jọ kọ ọ́.

Àwọn Arákùnrin àti Arábìnrin Wa Ń Mú Ká Lókun

Jẹ́ kí àwọn ọmọ rẹ mọ bí wọ́n ṣe lè ran àwọn ọ̀rẹ́ wọn lọ́wọ́ àti bí àwọn ọ̀rẹ́ wọn ṣe lè ran àwọn náà lọ́wọ́.