Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe àwọn fídíò eré bèbí tó ń kọ́ àwọn ọmọdé bí wọ́n á ṣe máa tẹ̀ lé àwọn ìlànà inú Bíbélì. Báwo la ṣe ń ṣe àwọn fídíò yìí, báwo ni àwọn ọmọdé sì ṣe ń gbádùn rẹ̀ sí? Wàá rí ìdáhùn tó o bá wo fídíò yìí.