Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Jẹ́ Ẹni Tó Moore: Orin àti Ọ̀rọ̀ Orin

Ẹ̀yin ọmọ, ṣé ẹ máa ń jẹ́ káwọn òbí yín mọ bí ẹ ṣe nífẹ̀ẹ́ wọn tó? Wa ìwé orin yìí jáde, kó o wá máa bá Tosin kọrin bó ṣe ń kọrin fún àwọn òbí rẹ̀.

Tún Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Jẹ́ Ẹni Tó Moore

Báwo lo ṣe lè jẹ́ káwọn tó ràn ẹ́ lọ́wọ́ mọ̀ pé o mọ rírì ohun tí wọ́n ṣe fún ẹ?