Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

Dúpẹ́ Pé Ọlọ́run Dá Òjò

Àwọn ọmọ tí kò tíì ju ọmọ ọdún mẹ́ta lọ la kọ ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí fún. Wa ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí jáde, kó o sì kà á pẹ̀lú ọmọ rẹ.

 

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Dáníẹ́lì Gbàdúrà!

Kọ́ ọmọ rẹ bó ṣe ṣe pàtàkì tó láti máa gbàdúrà sí Ọlọ́run lójoojúmọ́.

Jésù, Ọmọ Jòjòló

Kọ́ ọmọ rẹ kékeré nípa ìbí Jésù.

Àwọn Hébérù Mẹ́ta

Jẹ́ kí ọmọ rẹ mọ ìdí tí Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò fi kọ̀ láti forí balẹ̀ fún ère oníwúrà tí ọba ṣe.