Àwọn ọmọ tí kò tíì ju ọmọ ọdún mẹ́ta lọ la kọ ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí fún. Wa ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí jáde, kó o sì kà á pẹ̀lú ọmọ rẹ.