Kí nìdí tí Rúùtù kò fi pa dà sí ìlú ìbílẹ̀ rẹ̀, tó fi jẹ́ pé ìlú míì ló gbà lọ? Ka ọ̀rọ̀ inú àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.