Kẹ́kọ̀ọ́ nípa Nóà, ẹni tó kọ́ áàkì ńlá kan kó lè gba ìdílé rẹ̀ àtàwọn ẹranko là. Ka ọ̀rọ̀ inú àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.