Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

Jèhófà Fún Sólómọ́nì ní Ọgbọ́n

Nínú ìtàn Bíbélì yìí, wàá kọ́ nípa bí Ọba Sólómọ́nì ṣe di ọlọ́gbọ́n, àmọ́ tó wá ṣàṣìṣe nígbà tó yá. Ka ọ̀rọ̀ inú àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Jèhófà Máa Ń Dárí Jini Pátápátá

Ọba Mánásè pidán, ó forí balẹ̀ fún òrìṣà, ó sì pa àwọn èèyàn tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀. Síbẹ̀, Jèhófà ṣe tán láti dárí jì í. Kí ni ìtàn yìí kọ́ wa nípa ìdáríjì?

Nóà Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run

Ọlọ́run pàṣẹ fún Nóà pé kó kọ́ áàkì kan kí ìdílé rẹ̀ má bàa pa run nígbà Ìkún Omi, ó sì ṣe bẹ́ẹ̀. Kí ni ìtàn Nóà àti Ìkún Omi kọ́ ẹ nípa ìdí tó fi yẹ ká nígbàgbọ́ nínú Ọlọ́run?

Ábúráhámù Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run

Ọlọ́run pe Ábúráhámù ní ọ̀rẹ́ rẹ̀. Báwo la ṣe lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?