Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àwọn Àwòrán Ìtàn Bíbélì

Ó máa dà bíi pé o wà níbi tí àwọn ìtàn Bíbélì ti ṣẹlẹ̀ bó o ṣe ń kà wọ́n pẹ̀lú àwòrán wọn lórí ìkànnì wa tàbí lẹ́yìn tó o bá tẹ̀ wọ́n jáde. Lẹ́yìn náà, kí ìdílé rẹ lo àwọn ìbéèrè tó wà ní ìparí ìtàn náà láti fi jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ tẹ́ ẹ rí kọ́ nínú rẹ̀.