Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Àwọn Ìwà àti Àṣà Tó Ti Di Bárakú

Ìwà Rẹ

Àwọn Àṣà Tó Lè Ṣe Ẹ́ Láǹfààní

Rí i dájú pé àwọn àṣà rẹ ń ṣe ẹ́ láǹfààní dípò tá á fi kó bá ẹ.

Ṣé Ó Fi Bẹ́ẹ̀ Burú Kéèyàn Máa Ṣépè?

Kéèyàn máa ṣépè kì í ṣe ohun tuntun, àmọ́ ṣé ó burú?

Ǹjẹ́ Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ Ń Fẹ́ Kó O Ṣe Ohun Tó Burú?

Kọ́ àwọn ohun tó o lè ṣe láti yẹra fún nǹkan náà tàbí kó o mú nǹkan náà kúrò pátápátá.

Oògùn Olóró àti Ọtí Líle

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Ọtí? Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Kí Èèyàn Máa Mu Ọtí?

Bíbélì sọ ohun tó dára nípa wáìnì àti ọtí.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ọtí?

Mọ ohun tó o lè ṣe kí ọwọ́ òfin má bàa tẹ̀ ẹ́, kí orúkọ ẹ má bà jẹ́ tàbí kí wọ́n má bàa fipá bá ẹ lò pọ̀, kí ọtí má sì di bárakú fún ẹ tàbí kó o fẹ̀mí ara ẹ ṣòfò.

Ojú Wo ni Ọlọ́run fi Ń Wo Sìgá Mímu?

Báwo la ṣe máa mọ̀ nígbà tí Bíbélì ò dárúkọ sìgá?

Ọ̀rọ̀ Ara Mi Sú Mi

Ọ̀mùtí paraku ni Dmitry Korshunov, àmọ́ ó bẹ̀rẹ̀ sí í ka Bíbélì déédéé. Kí ló mú kó yí ìgbésí ayé rẹ̀ pa dà?

Àwọn Ẹ̀rọ Ìgbàlódé

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Àwọn Géèmù Orí Kọ̀ǹpútà?

O lè má tíì ronú nípa àǹfààní tó lè ṣe ẹ́ àti àkóbá tó lè ṣe fún ẹ.

Ṣé Fóònù tàbí Tablet Ò Tíì Di Bárakú fún Ẹ?

Ayé ti di ayé íńtánẹ́ẹ̀tì, àmọ́ kò yẹ kó di bárakú fún ẹ. Báwo lo ṣe lè mọ̀ tí fóònù tàbí tablet bá ti di bárakú fún ẹ? Ká sọ pé ó ti di bárakú fún ẹ, kí lo lè ṣe sí i?

Tẹ́tẹ́

Ohun Ti Bibeli So Nipa Tete Tita

Se ere owo lasan ni?

Ṣé Ẹ̀ṣẹ̀ Ni Tẹ́tẹ́ Títa?

Bíbélì ò ṣe kúlẹ̀kúlẹ̀ àlàyé nípa tẹ́tẹ́ títa, báwo la ṣe wá lè mọ irú ojú tí Ọlọ́run fi ń wò ó?

Àwọn Ohun Tó Mú Ọkàn Fà sí Ìṣekúṣe

Àwòrán Oníhòòhò—Ó Léwu Àbí Kò Léwu?

Ọṣẹ́ wo ni àwòrán oníhòòhò ń ṣe fún ẹni tó ń wò ó àti fún ìdílé?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Yẹra fún Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe?

Kí ló jọra nínú wíwo àwòrán ìṣekúṣe àti mímu sìgá?

Ṣé Wíwo Ohun Tó Ń Mú Ọkàn Èèyàn Fà sí Ìṣekúṣe Ti Mọ́ Ẹ Lára?

Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀ pé ohun tó ń mú ọkàn èèyàn fà sí ìṣekúṣe kò dára.