Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Àlàáfíà àti Ayọ̀

Tá a bá dojú kọ àwọn ìṣòro ńlá, ó lè máa ṣe wá bíi pé a ò lè láyọ̀ mọ́ tàbí pé a ò lè ní ìfọ̀kànbalẹ̀. Síbẹ̀, Bíbélì ti ran ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lọ́wọ́ láti fara da wàhálà ojoojúmọ́ tó ń bá wọn, ó ti jẹ́ kí ara tù wọ́n, ó sì ti bá wọn mú ẹ̀dùn ọkàn wọn kúrò. Yàtọ̀ síyẹn, ó ti jẹ́ kí ìgbésí ayé wọn nítumọ̀, ó sì ti jẹ́ káyé wọn dáa sí i. Bíbélì lè ran ìwọ náà lọ́wọ́ kó o lè láyọ̀.

Ìtẹ̀jáde

Nígbà Tí Ẹnìkan Tí Ìwọ Fẹ́ràn Bá Kú

Ṣé ẹnì kan tó o fẹ́ràn kú? Ṣé o nílò ìrànlọ́wọ́ láti kojú ẹ̀dùn ọkàn rẹ?

Ìdílé Rẹ Lè Jẹ́ Aláyọ̀

O lè ní ìgbeyàwó àti ìdílé tó láyọ̀ tó o bá ń fi àwọn ìlànà Bíbélì sílò.

Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́dọ̀ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Bíbélì ń ran ọ̀pọ̀ mílíọ̀nù èèyàn lọ́wọ́ kárí ayé láti rí ìdáhùn sáwọn ìbéèrè tó ṣe pàtàkì jù lọ. Ṣé wàá fẹ́ jẹ́ ọ̀kan lára wọn?

Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?

Níbi gbogbo kárí ayé láwọn èèyàn ti mọ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà mọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí wọ́n máa ń ṣe fáwọn èèyàn lọ́fẹ̀ẹ́. Wo bí wọ́n ṣe máa ń ṣe é.

Béèrè Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́ ní àkókò àti ibi tó rọrùn fún ẹ.