Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Kí Lo Lè Sọ Nínú Àdúrà Rẹ Lónìí?

Kí lo lè ṣe tí wàá fi máa rí ohun tuntun sọ tó o bá ń gbàdúrà ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan?

Tún Wo

DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Gbàdúrà Nígbà Gbogbo

Fídíò tó ṣeé wà jáde yìí máa jẹ́ káwọn ọmọdé mọ ìgbà tí wọ́n lè gbàdúrà sí Jèhófà àti ibi tí wọ́n ti lè gbàdúrà.

ERÉ DI Ọ̀RẸ́ JÈHÓFÀ

Gbàdúrà Nígbà Gbogbo: Orin àti Ọ̀rọ̀ Orin

Wa abala orin yìí jáde tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde. Àwọn ọmọdé máa fẹ́ràn orin tó rọrùn láti kọ́ yìí!