Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ

Sámúẹ́lì Yàn Láti Sin Jèhófà

Kí ni ọmọdékùnrin Sámúẹ́lì ṣe, nígbà tí àwọn tó yí i ká kò bọ̀wọ̀ fún Ọlọ́run? Ka ọ̀rọ̀ inú àwòrán ìtàn Bíbélì yìí lórí ìkànnì wa tàbí kó o tẹ̀ ẹ́ jáde.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Jèhófà Fún Sólómọ́nì ní Ọgbọ́n

Kò sí ọba tó ní ọgbọ́n tó Sólómọ́nì láyé yìí. Báwo ló ṣe di ọlọ́gbọ́n? Àwọn àṣìṣe wo ló sì ṣe nígbà tó yá?

Nóà Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run

Ọlọ́run pàṣẹ fún Nóà pé kó kọ́ áàkì kan kí ìdílé rẹ̀ má bàa pa run nígbà Ìkún Omi, ó sì ṣe bẹ́ẹ̀. Kí ni ìtàn Nóà àti Ìkún Omi kọ́ ẹ nípa ìdí tó fi yẹ ká nígbàgbọ́ nínú Ọlọ́run?

Ábúráhámù Di Ọ̀rẹ́ Ọlọ́run

Ọlọ́run pe Ábúráhámù ní ọ̀rẹ́ rẹ̀. Báwo la ṣe lè di ọ̀rẹ́ Ọlọ́run?