Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÌWÉ ÀJÁKỌ FÚN ÀWỌN Ọ̀DỌ́

ÌWÉ ÀJÁKỌ

Jẹ́ Kí Ohun Tó ò Gbàgbọ́ Dá Ọ Lójú: Kéèyàn Ma Tíì Ní Ìbálòpọ̀ Rí | Ìwé Àjákọ fún Àwọn Ọ̀dọ́

Ìwé àjákọ tó máa mú kí ìpinnu tó o ṣe láti tẹ̀ lé òfin Ọlọ́run nípa ìbálòpọ̀ ṣáájú ìgbéyàwó túbọ̀ fẹsẹ̀ múlẹ̀.

Àwọn Nǹkan Míì Nínú Ọ̀wọ́ Yìí

Fọ́tò Rẹ Lórí Ìkànnì Ń Sọ Irú Ẹni Tó O Jẹ́

Wo ohun tó yẹ kó o rò kó o tó gbé fọ́tò ẹ sórí ìkànnì.

Bó O Ṣe Lè Máa Fi Àyè Àṣìṣe Sílẹ̀

Ìwé yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ kó o lè mọ bó ò ṣe ní máa retí ohun tó pọ̀ jù lọ́wọ́ ara ẹ àti lọ́wọ́ àwọn míì.

Bí O Ṣe Lè Mú Kí Àdúrà Rẹ Sunwọ̀n Sí I

Ìwé yìí á jẹ́ kó o ṣàyẹ̀wò àwọn nǹkan tó o máa ń sọ nínú àdúrà rẹ àti bí àdúrà tó ò ń gbà sí Ọlọ́run ṣe nítumọ̀ tó.